Abàmì ẹlẹ́dẹ̀ tí dífá fún Super Eagles nípa Russia 2018 Olayemi Oniroyin 6/15/2018 05:51:00 pm Add Comment Edit Ẹlẹ́dẹ̀ abàmì tó sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa wí pé, Donald J. Trump ìlú Amẹrika ni yóò jaye olubori gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ ilẹ̀ Amẹ́ríkà tí kéde wí pé ikọ́ a... Read More
Russia 2018: Pele àti Maradona tí wọlé Olayemi Oniroyin 6/12/2018 07:53:00 am Add Comment Edit Ààrẹ ìlú Russia 🇷🇺, Putin, fún ra rẹ lo kí Pele kaabọ si orile-ede Russia fún igbaradi ìfẹ́ agbaye tí yóò wayé ni or... Read More
"Mikel Obi kìí rán àwọn ènìyàn rẹ lọ́wọ́"- Ẹbi Mikel kan tí sọ̀rọ̀ Olayemi Oniroyin 5/10/2018 06:33:00 pm Add Comment Edit Ọmọkùnrin kan lórí ayélujára ti gbìyànjú láti fi aṣọ Mikel Obi yidọti. Ọmọkùnrin náà ṣe àlàyé ara rẹ gẹ́gẹ́ bí ọmọ àbúrò bàbà Mikel. Ó ni ar... Read More
Arsene Wenger tí kéde ifehinti rẹ Olayemi Oniroyin 4/23/2018 02:22:00 pm Add Comment Edit Ẹ kíyèsí, àlàyé to bá ti ní nọ́mbà kìí rújú. Nǹkan bí ọdún méjìlélógún lo fi tukọ̀ ẹgbẹ́ agbaboolu Arsenal gẹ́gẹ́ bí akonimọọgba. Igba mẹta ... Read More
Ọwọ Anthony Joshua, ọmọ ológo, ni àgbà wá báyìí Olayemi Oniroyin 4/01/2018 01:40:00 pm Add Comment Edit Ẹ wí fún ẹni tí kò bá mọ kí wọn lọ mọ wí pé, ọwọ́ Anthony Oluwafemi Olaseni Joshua nìkan ni ẹ ti lè rí àmì ẹyẹ agbaye WBA, IBF, WBO ati IBO.... Read More
Anthony Joshua Oluwafemi to bẹru Olayemi Oniroyin 4/01/2018 12:46:00 am Add Comment Edit Anthony Olaseni Oluwafemi Joshua ṣe àfihàn àwọn àmì ẹyẹ rẹ lẹ́yìn to fo gbogbo ẹnu Joseph Parker nínú ìjà to wáyé lọjọ Satide, 31/03 /2018 ... Read More
Jatijati ni Anthony Joshua na Joseph Parker ni àlè ana Olayemi Oniroyin 4/01/2018 12:23:00 am Add Comment Edit Ninu idije ese kíkan tó wáyé ní ilẹ Biritiko lọjọ Satide to kẹyin oṣù kẹta, 31/03/2018, àná fò lójú ni Anthony Joshua na Joseph Parker Read More
A má tí orí Morocco bonu omi gbígbóná ni to bá di Sunday - Super Eagles Olayemi Oniroyin 2/02/2018 08:57:00 am Add Comment Edit Asekagba idije Chan 2018 eléyìí to ń wáyé ní orileede Morocco ni yóò wá sopin lọjọ Sande tí ń bo yii. Asekagba náà yóò sì wáyé láàárín Sup... Read More
C. Ronaldo kò àwọn ẹbí rẹ wọnú omi Olayemi Oniroyin 2/01/2018 11:03:00 am Add Comment Edit Omo to bá ń sise dééde, ó yẹ kó ni asiko isimi. Kosi sì ohun tó dùn bí kí ènìyàn ló isimi rẹ pẹlu awọn ẹbi rẹ. C Ronaldo lọ ṣe àfihàn òun à... Read More
Awon foto eto igbeyawo Lionel Messi ati aya re ni Argentina Olayemi Oniroyin 7/01/2017 08:58:00 am Add Comment Edit Gbogbo orileede Argentina lo mi titi nigba ti awon irawo agbaboolu kaakiri agbaye si baalu wole kaakiri origun meererin agbaye nibi ti ... Read More
Jay Jay Okocha pidan niluu Kenya Olayemi Oniroyin 3/23/2017 05:47:00 pm Add Comment Edit Leyin aimoye odun ti Jay Jay Okocha ti fi ere boolu alafesegba sile, omokunrin naa fi ye won niluu Kenya wi pe idan si ku lara re pel... Read More
Awon agba iyanu foto lati bi ere idaraya Olayemi Oniroyin 3/22/2017 01:31:00 pm Add Comment Edit Read More
Asisat Oshoala: Agbaboolu Obirin to pegede julo fodun 2016 Olayemi Oniroyin 1/07/2017 12:50:00 pm Add Comment Edit Asisat Oshoala, agbaboolu obirin omo ile Naijiria ti gba ami-ẹyẹ agbaboolu obirin ilẹ adulawo to dara ju fun odun 2016 ti ami ẹyẹ CAF Aw... Read More
Rigobert Song leyin osu meji nile iwosan Olayemi Oniroyin 12/05/2016 05:03:00 pm Add Comment Edit Agbaọjẹ agbaboolu tẹlẹ ri fun ilẹ Cameroon, Rigobert Song, la gbọ wi pe o ti n gbadun bayii lẹyin osu meji to lo ni ile iwosan ilu Faran... Read More
Oniroyin Jide Alabi bimo lonii ayajo ominira Olayemi Oniroyin 10/01/2016 01:49:00 pm Add Comment Edit Ogbontarigi osere onitiata to tun je oniroyin ere idaraya bimo tuntun lonii to je ayajo ojo ominira Naijiria. Omobirin ni omo naa eleyii... Read More
E wa wo ohun ti won se soju JJ Okocha agbaboolu Olayemi Oniroyin 9/24/2016 11:37:00 am Add Comment Edit Ise owo 'Hakeemeffect' ni, asarologe ti n se wondeful. O so oju JJ Okocha di baba arugbo. Oju agbalagba ti won se fun ... Read More
Cristiano Ronaldo tun ti gba gbogbo irawo agbaboolu to dara ju lo ti Europe patapata Olayemi Oniroyin 8/26/2016 09:52:00 am Add Comment Edit Cristiano Ronaldo O wu Edumare lo sori ewa fakuko. Sebi won ba Oya ja lasan ni, Sango lo ni seere. won ti gbe ami eye agbaboolu to da... Read More
Asiri ohun ti Cristiano Ronaldo n se to fi derujẹjẹ ni yii Olayemi Oniroyin 8/19/2016 10:33:00 pm Add Comment Edit Gege bi alaye awon onwoye, ati doke ko nira bi ati duro soke nigba gbogbo. Aimoye awon eniyan ni won simi sara latari okiki ati iyi... Read More